2 Kíróníkà 31:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yàtọ̀ síyẹn, ó pàṣẹ fún àwọn tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù pé kí wọ́n fún àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì ní apá tó tọ́ sí wọn,+ kí wọ́n lè gbájú mọ́ òfin Jèhófà.*
4 Yàtọ̀ síyẹn, ó pàṣẹ fún àwọn tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù pé kí wọ́n fún àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì ní apá tó tọ́ sí wọn,+ kí wọ́n lè gbájú mọ́ òfin Jèhófà.*