-
Léfítíkù 14:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ní ọjọ́ keje, kó fá gbogbo irun orí rẹ̀ àti àgbọ̀n rẹ̀ àti irun ojú rẹ̀. Tó bá ti fá gbogbo irun rẹ̀, kó fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, yóò sì di mímọ́.
-
-
Nọ́ńbà 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kí onítọ̀hún fi omi náà* wẹ ara rẹ̀ mọ́ ní ọjọ́ kẹta, yóò sì di mímọ́ ní ọjọ́ keje. Àmọ́ tí kò bá wẹ ara rẹ̀ mọ́ ní ọjọ́ kẹta, kò ní di mímọ́ ní ọjọ́ keje.
-