Sáàmù 106:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wọ́n múnú bí I níbi omi Mẹ́ríbà,*Wọ́n sì fi tiwọn kó bá Mósè.+ 33 Wọ́n gbé ẹ̀mí rẹ̀ gbóná,Ó sì fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ láìronú.+
32 Wọ́n múnú bí I níbi omi Mẹ́ríbà,*Wọ́n sì fi tiwọn kó bá Mósè.+ 33 Wọ́n gbé ẹ̀mí rẹ̀ gbóná,Ó sì fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ láìronú.+