- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 14:45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        45 Àwọn ọmọ Ámálékì àti àwọn ọmọ Kénáánì tí wọ́n ń gbé ní òkè yẹn wá sọ̀ kalẹ̀, wọ́n bá wọn jà, wọ́n sì ń tú wọn ká títí lọ dé Hóómà.+ 
 
-