Nọ́ńbà 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ló dé tí ẹ kó wa kúrò ní Íjíbítì wá sí ibi burúkú yìí?+ Irúgbìn, ọ̀pọ̀tọ́, àjàrà àti pómégíránétì ò lè hù níbí, bẹ́ẹ̀ ni kò sí omi tá a lè mu.”+
5 Kí ló dé tí ẹ kó wa kúrò ní Íjíbítì wá sí ibi burúkú yìí?+ Irúgbìn, ọ̀pọ̀tọ́, àjàrà àti pómégíránétì ò lè hù níbí, bẹ́ẹ̀ ni kò sí omi tá a lè mu.”+