Jòhánù 3:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àti pé bí Mósè ṣe gbé ejò sókè ní aginjù,+ bẹ́ẹ̀ náà la gbọ́dọ̀ gbé Ọmọ èèyàn sókè,+ 15 kí gbogbo ẹni tó bá gbà á gbọ́ lè ní ìyè àìnípẹ̀kun.+
14 Àti pé bí Mósè ṣe gbé ejò sókè ní aginjù,+ bẹ́ẹ̀ náà la gbọ́dọ̀ gbé Ọmọ èèyàn sókè,+ 15 kí gbogbo ẹni tó bá gbà á gbọ́ lè ní ìyè àìnípẹ̀kun.+