21 Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá fi Síhónì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́, torí náà wọ́n ṣẹ́gun wọn, Ísírẹ́lì sì gba gbogbo ilẹ̀ àwọn Ámórì tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ 22 Bí wọ́n ṣe gba gbogbo ilẹ̀ àwọn Ámórì nìyẹn, láti Áánónì dé Jábókù àti láti aginjù títí dé Jọ́dánì.+