- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 6:77Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        77 Látinú ẹ̀yà Sébúlúnì,+ wọ́n fún àwọn ọmọ Mérárì tó ṣẹ́ kù ní Rímónò pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Tábórì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀; 
 
-