- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 31:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Wọ́n bá Mídíánì jagun, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin. 8 Yàtọ̀ sí àwọn tí wọ́n pa, wọ́n tún pa àwọn ọba Mídíánì, ìyẹn Éfì, Rékémù, Súúrì, Húrì àti Rébà, àwọn ọba Mídíánì márààrún. Wọ́n tún fi idà pa Báláámù+ ọmọ Béórì. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóṣúà 13:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 Mósè pín ogún fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ní ìdílé-ìdílé, 
 
-