-
Nọ́ńbà 22:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ sùn síbí mọ́jú, ohunkóhun tí Jèhófà bá sọ fún mi, màá wá sọ fún yín.” Àwọn ìjòyè Móábù sì dúró sọ́dọ̀ Báláámù.
-