ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 23:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Bálákì sọ fún un pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ ká lọ sí ibòmíì tí o ti lè rí wọn. Díẹ̀ nínú wọn ni wàá rí; o ò ní rí gbogbo wọn. Bá mi gégùn-ún fún wọn láti ibẹ̀.”+ 14 Torí náà, ó mú un lọ sí pápá Sófímù, ní orí Písígà,+ ó mọ pẹpẹ méje, ó sì fi akọ màlúù kan àti àgbò kan rúbọ lórí pẹpẹ+ kọ̀ọ̀kan.

  • Nọ́ńbà 23:28-30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Bálákì wá mú Báláámù lọ sí orí òkè Péórì, tó dojú kọ Jéṣímónì.*+ 29 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Mọ pẹpẹ méje sí ibí yìí, kí o sì pèsè akọ màlúù méje àti àgbò méje sílẹ̀ fún mi.”+ 30 Bálákì wá ṣe ohun tí Báláámù sọ gẹ́lẹ́, ó sì fi akọ màlúù kan àti àgbò kan rúbọ lórí pẹpẹ kọ̀ọ̀kan.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́