-
Nọ́ńbà 23:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ó wá sọ̀rọ̀ lówelówe pé:+
“Dìde Bálákì, kí o sì fetí sílẹ̀.
Tẹ́tí sí mi, ìwọ ọmọ Sípórì.
-
-
Nọ́ńbà 24:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ó sì sọ̀rọ̀ lówelówe pé: +
“Ọ̀rọ̀ Báláámù ọmọ Béórì,
Àti ọ̀rọ̀ ẹnu ọkùnrin tí ojú rẹ̀ ti là,
-