- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 8:53Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        53 Nítorí o ti yà wọ́n sọ́tọ̀ láti jẹ́ ogún rẹ nínú gbogbo aráyé,+ bí o ṣe gba ẹnu Mósè ìránṣẹ́ rẹ sọ̀rọ̀, nígbà tí ò ń mú àwọn baba ńlá wa jáde kúrò ní Íjíbítì, ìwọ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.” 
 
-