1 Sámúẹ́lì 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Yàtọ̀ síyẹn, Atóbilọ́lá Ísírẹ́lì+ kò ní jẹ́ parọ́+ tàbí kó yí ìpinnu rẹ̀ pa dà,* nítorí Òun kì í ṣe èèyàn tí á fi yí ìpinnu rẹ̀ pa dà.”*+
29 Yàtọ̀ síyẹn, Atóbilọ́lá Ísírẹ́lì+ kò ní jẹ́ parọ́+ tàbí kó yí ìpinnu rẹ̀ pa dà,* nítorí Òun kì í ṣe èèyàn tí á fi yí ìpinnu rẹ̀ pa dà.”*+