-
1 Sámúẹ́lì 19:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ní kíá, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ láti lọ mú Dáfídì. Nígbà tí wọ́n rí àwọn tó dàgbà lára àwọn wòlíì tí wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀, tí Sámúẹ́lì sì dúró tó ń ṣe olórí wọn, ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé àwọn òjíṣẹ́ Sọ́ọ̀lù, àwọn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe bíi wòlíì.
-