Jẹ́nẹ́sísì 36:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ísọ̀ wá ń gbé ní agbègbè olókè Séírì.+ Ísọ̀ ni Édómù.+ Jóṣúà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+
4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+