Sáàmù 106:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ nígbà tí Fíníhásì dìde, tí ó sì dá sí i,Àjàkálẹ̀ àrùn náà dáwọ́ dúró.+ 31 A sì kà á sí òdodo fún unLáti ìran dé ìran àti títí láé.+
30 Àmọ́ nígbà tí Fíníhásì dìde, tí ó sì dá sí i,Àjàkálẹ̀ àrùn náà dáwọ́ dúró.+ 31 A sì kà á sí òdodo fún unLáti ìran dé ìran àti títí láé.+