-
Léfítíkù 25:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Tí ẹ bá ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì ń tẹ̀ lé àwọn ìdájọ́ mi, ẹ máa gbé ilẹ̀ náà láìséwu.+
-
-
Diutarónómì 30:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú ọ wá sí ilẹ̀ tí àwọn bàbá rẹ gbà, ó sì máa di tìẹ; á mú kí nǹkan máa lọ dáadáa fún ọ, á sì mú kí o pọ̀ ju àwọn bàbá+ rẹ.
-