Diutarónómì 32:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Torí èyí kì í ṣe ọ̀rọ̀ tí kò wúlò fún yín, àmọ́ òun ló máa mú kí ẹ wà láàyè,+ ọ̀rọ̀ yìí sì máa mú kí ẹ̀mí yín gùn lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”
47 Torí èyí kì í ṣe ọ̀rọ̀ tí kò wúlò fún yín, àmọ́ òun ló máa mú kí ẹ wà láàyè,+ ọ̀rọ̀ yìí sì máa mú kí ẹ̀mí yín gùn lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”