-
1 Àwọn Ọba 11:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ohun tí màá ṣe nìyí torí pé wọ́n ti fi mí sílẹ̀,+ wọ́n sì ń forí balẹ̀ fún Áṣítórétì, abo ọlọ́run àwọn ọmọ Sídónì, fún Kémóṣì, ọlọ́run Móábù àti fún Mílíkómù, ọlọ́run àwọn ọmọ Ámónì, wọn ò rìn ní àwọn ọ̀nà mi láti máa ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi àti láti máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́ bí Dáfídì bàbá Sólómọ́nì ti ṣe.
-