Diutarónómì 31:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá dé bá wọn,+ orin yìí máa jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wọn, (torí àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò gbọ́dọ̀ gbàgbé rẹ̀), torí mo ti mọ ohun tí wọ́n ń rò lọ́kàn+ kí n tiẹ̀ tó mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀.”
21 Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá dé bá wọn,+ orin yìí máa jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wọn, (torí àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò gbọ́dọ̀ gbàgbé rẹ̀), torí mo ti mọ ohun tí wọ́n ń rò lọ́kàn+ kí n tiẹ̀ tó mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀.”