Nọ́ńbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+ Diutarónómì 31:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Ọjọ́ ikú rẹ ti sún mọ́lé.+ Pe Jóṣúà, kí ẹ sì lọ síwájú* àgọ́ ìpàdé, kí n lè faṣẹ́ lé e lọ́wọ́.”+ Mósè àti Jóṣúà wá lọ síwájú àgọ́ ìpàdé.
18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+
14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Ọjọ́ ikú rẹ ti sún mọ́lé.+ Pe Jóṣúà, kí ẹ sì lọ síwájú* àgọ́ ìpàdé, kí n lè faṣẹ́ lé e lọ́wọ́.”+ Mósè àti Jóṣúà wá lọ síwájú àgọ́ ìpàdé.