Diutarónómì 32:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Mósè ka gbogbo ọ̀rọ̀ orin yìí sí àwọn èèyàn+ náà létí, òun àti Hóṣéà*+ ọmọ Núnì.