Sáàmù 78:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run. Lúùkù 9:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Jésù fèsì pé: “Ìran aláìnígbàgbọ́ àti oníbékebèke,+ títí dìgbà wo ni màá fi wà pẹ̀lú yín, tí màá sì máa fara dà á fún yín? Mú ọmọkùnrin rẹ wá síbí.”+
8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.
41 Jésù fèsì pé: “Ìran aláìnígbàgbọ́ àti oníbékebèke,+ títí dìgbà wo ni màá fi wà pẹ̀lú yín, tí màá sì máa fara dà á fún yín? Mú ọmọkùnrin rẹ wá síbí.”+