ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hósíà 2:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Màá gbìn ín bí irúgbìn fún ara mi sórí ilẹ̀,+

      Màá sì ṣàánú rẹ̀, bí wọn ò tiẹ̀ ṣàánú rẹ̀;*

      Màá sọ fún àwọn tí kì í ṣe èèyàn mi pé:* “Èèyàn mi ni yín”,+

      Àwọn náà á sì sọ pé: “Ìwọ ni Ọlọ́run wa.”’”+

  • Róòmù 9:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ó rí bí ó ṣe sọ nínú ìwé Hósíà pé: “Màá pe àwọn tí kì í ṣe èèyàn mi+ ní ‘àwọn èèyàn mi,’ màá sì pe ẹni tí kì í ṣe olùfẹ́ ní ‘àyànfẹ́’;+

  • Róòmù 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí náà, mo béèrè pé, Ṣé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọsẹ̀ tí wọ́n fi ṣubú pátápátá ni? Rárá o! Àmọ́ bí wọ́n ṣe ṣi ẹsẹ̀ gbé ló mú ìgbàlà wá fún àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè, èyí sì mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa jowú.+

  • 1 Pétérù 2:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí ẹ kì í ṣe àwùjọ èèyàn nígbà kan, àmọ́ ní báyìí ẹ ti di àwùjọ èèyàn Ọlọ́run;+ a kò ṣàánú yín nígbà kan, àmọ́ ní báyìí, a ti ṣàánú yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́