Róòmù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé Ísírẹ́lì ò mọ̀ ni?+ Wọ́n kúkú mọ̀. Lákọ̀ọ́kọ́, Mósè sọ pé: “Màá fi àwọn tí kì í ṣe orílẹ̀-èdè mú kí ẹ jowú; màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀ mú kí ẹ gbaná jẹ.”+
19 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé Ísírẹ́lì ò mọ̀ ni?+ Wọ́n kúkú mọ̀. Lákọ̀ọ́kọ́, Mósè sọ pé: “Màá fi àwọn tí kì í ṣe orílẹ̀-èdè mú kí ẹ jowú; màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀ mú kí ẹ gbaná jẹ.”+