Émọ́sì 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n bá walẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,*Ibẹ̀ ni ọwọ́ mi á ti tẹ̀ wọ́n;Bí wọ́n bá sì gòkè lọ sí ọ̀run,Ibẹ̀ ni màá ti fà wọ́n sọ̀ kalẹ̀.
2 Bí wọ́n bá walẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,*Ibẹ̀ ni ọwọ́ mi á ti tẹ̀ wọ́n;Bí wọ́n bá sì gòkè lọ sí ọ̀run,Ibẹ̀ ni màá ti fà wọ́n sọ̀ kalẹ̀.