Nọ́ńbà 32:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Torí náà, Mósè fún Mákírù ọmọ Mánásè ní Gílíádì, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀.+ 41 Jáírì ọmọ Mánásè lọ síbẹ̀ láti gbógun jà wọ́n, ó sì gba àwọn abúlé tí wọ́n pàgọ́ sí, ó wá pè wọ́n ní Hafotu-jáírì.*+
40 Torí náà, Mósè fún Mákírù ọmọ Mánásè ní Gílíádì, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀.+ 41 Jáírì ọmọ Mánásè lọ síbẹ̀ láti gbógun jà wọ́n, ó sì gba àwọn abúlé tí wọ́n pàgọ́ sí, ó wá pè wọ́n ní Hafotu-jáírì.*+