2 Kíróníkà 24:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọmọ ogun ará Síríà tó ya wá kò pọ̀, Jèhófà fi ọmọ ogun tó pọ̀ gan-an lé wọn lọ́wọ́,+ nítorí wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀; torí náà, wọ́n* mú ìdájọ́ ṣẹ sórí Jèhóáṣì.
24 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọmọ ogun ará Síríà tó ya wá kò pọ̀, Jèhófà fi ọmọ ogun tó pọ̀ gan-an lé wọn lọ́wọ́,+ nítorí wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀; torí náà, wọ́n* mú ìdájọ́ ṣẹ sórí Jèhóáṣì.