ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbàkigbà tí Jèhófà bá yan àwọn onídàájọ́ fún wọn,+ Jèhófà máa ń wà pẹ̀lú onídàájọ́ náà, ó sì máa ń gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn ní gbogbo ọjọ́ tí onídàájọ́ náà bá fi wà; Jèhófà ṣàánú wọn*+ torí pé àwọn tó ń ni wọ́n lára+ àtàwọn tó ń fìyà jẹ wọ́n mú kí wọ́n máa kérora.

  • Sáàmù 90:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Pa dà, Jèhófà!+ Ìgbà wo ni èyí máa dópin?+

      Ṣàánú àwọn ìránṣẹ́ rẹ.+

  • Sáàmù 106:45
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Nítorí wọn, á rántí májẹ̀mú rẹ̀,

      Àánú á sì ṣe é* nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tó ga tí kì í sì í yẹ̀.*+

  • Sáàmù 135:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí Jèhófà yóò gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀,*+

      Yóò sì ṣàánú* àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́