-
Nọ́ńbà 12:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Mósè wá bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà, ó ní: “Ọlọ́run, jọ̀ọ́ mú un lára dá! Jọ̀ọ́!”+
-
-
Jeremáyà 17:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wò mí sàn, Jèhófà, ara mi á sì dá.
Gbà mí là, màá sì rí ìgbàlà,+
Nítorí ìwọ ni èmi yóò máa yìn.
-