Nọ́ńbà 34:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ààlà náà lọ láti Ṣẹ́fámù dé Ríbúlà ní ìlà oòrùn Áyínì, kí ààlà náà sì gba ìsàlẹ̀ lọ kan gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ ìlà oòrùn Òkun Kínérétì.*+ 12 Kí ààlà náà lọ dé Jọ́dánì, kó sì parí sí Òkun Iyọ̀.+ Èyí ni yóò jẹ́ ilẹ̀+ yín àti àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.’”
11 Kí ààlà náà lọ láti Ṣẹ́fámù dé Ríbúlà ní ìlà oòrùn Áyínì, kí ààlà náà sì gba ìsàlẹ̀ lọ kan gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ ìlà oòrùn Òkun Kínérétì.*+ 12 Kí ààlà náà lọ dé Jọ́dánì, kó sì parí sí Òkun Iyọ̀.+ Èyí ni yóò jẹ́ ilẹ̀+ yín àti àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.’”