Léfítíkù 22:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹ ò gbọ́dọ̀ sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́,+ ṣe ni kí ẹ fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Èmi ni Jèhófà, ẹni tó ń sọ yín di mímọ́,+ Àìsáyà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ kà sí mímọ́,+Òun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ bẹ̀rù,Òun sì ni Ẹni tó yẹ kó mú kí ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì.”+
32 Ẹ ò gbọ́dọ̀ sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́,+ ṣe ni kí ẹ fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Èmi ni Jèhófà, ẹni tó ń sọ yín di mímọ́,+
13 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ kà sí mímọ́,+Òun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ bẹ̀rù,Òun sì ni Ẹni tó yẹ kó mú kí ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì.”+