- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 1:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        44 Èyí ni àwọn tí Mósè pẹ̀lú Áárónì àti àwọn ìjòyè méjìlá (12) Ísírẹ́lì forúkọ wọn sílẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ṣojú fún agbo ilé bàbá rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 1:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        46 gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+ 
 
-