-
Nọ́ńbà 26:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógójì ó lé ọgọ́rùn-ún méje àti ọgbọ̀n (43,730).+
-
-
Jóṣúà 13:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mósè pín ogún fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ní ìdílé-ìdílé,
-