- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 32:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        26 Lẹ́yìn náà, Mósè dúró ní ẹnubodè àgọ́ náà, ó sì sọ pé: “Ta ló fara mọ́ Jèhófà? Kó máa bọ̀ lọ́dọ̀ mi!”+ Gbogbo àwọn ọmọ Léfì sì kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀. 
 
-