Málákì 2:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ ó sì mọ̀ pé mo ti pa àṣẹ yìí fún yín, kí májẹ̀mú tí mo bá Léfì dá má bàa yẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. 5 “Májẹ̀mú ìyè àti àlàáfíà ni mo bá a dá, mo sì dá a kó lè bẹ̀rù* mi. Ó bẹ̀rù mi, àní, ó bẹ̀rù orúkọ mi.
4 Ẹ ó sì mọ̀ pé mo ti pa àṣẹ yìí fún yín, kí májẹ̀mú tí mo bá Léfì dá má bàa yẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. 5 “Májẹ̀mú ìyè àti àlàáfíà ni mo bá a dá, mo sì dá a kó lè bẹ̀rù* mi. Ó bẹ̀rù mi, àní, ó bẹ̀rù orúkọ mi.