Jẹ́nẹ́sísì 49:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Ní ti Gádì,+ àwọn jàǹdùkú* yóò jà á lólè, àmọ́ òun yóò kọ lù wọ́n ní gìgísẹ̀.+