- 
	                        
            
            Àwọn Onídàájọ́ 13:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        24 Lẹ́yìn náà, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ ọ́ ní Sámúsìn;+ bí ọmọ náà ṣe ń dàgbà, Jèhófà ń bù kún un. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Àwọn Onídàájọ́ 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 Ogún (20) ọdún+ ló fi jẹ́ onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì nígbà ayé àwọn Filísínì. 
 
-