Jóṣúà 19:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Àmọ́ ilẹ̀ Dánì ti kéré jù fún wọn.+ Torí náà, wọ́n lọ bá Léṣémù + jà, wọ́n gbà á, wọ́n sì fi idà ṣá wọn balẹ̀. Ó di tiwọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọ́n wá yí orúkọ Léṣémù pa dà sí Dánì, ìyẹn Dánì tó jẹ́ orúkọ baba ńlá wọn.+
47 Àmọ́ ilẹ̀ Dánì ti kéré jù fún wọn.+ Torí náà, wọ́n lọ bá Léṣémù + jà, wọ́n gbà á, wọ́n sì fi idà ṣá wọn balẹ̀. Ó di tiwọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọ́n wá yí orúkọ Léṣémù pa dà sí Dánì, ìyẹn Dánì tó jẹ́ orúkọ baba ńlá wọn.+