Jẹ́nẹ́sísì 49:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Náfútálì+ jẹ́ abo àgbọ̀nrín tó rí pẹ́lẹ́ńgẹ́. Ó ń sọ ọ̀rọ̀ tó dùn.+