Jẹ́nẹ́sísì 19:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Tètè sá lọ síbẹ̀! Torí mi ò lè ṣe nǹkan kan títí wàá fi dé ibẹ̀!”+ Ìdí nìyẹn tó fi pe orúkọ ìlú náà ní Sóárì.*+ 23 Oòrùn ti yọ ní ilẹ̀ náà nígbà tí Lọ́ọ̀tì dé Sóárì.
22 Tètè sá lọ síbẹ̀! Torí mi ò lè ṣe nǹkan kan títí wàá fi dé ibẹ̀!”+ Ìdí nìyẹn tó fi pe orúkọ ìlú náà ní Sóárì.*+ 23 Oòrùn ti yọ ní ilẹ̀ náà nígbà tí Lọ́ọ̀tì dé Sóárì.