Diutarónómì 32:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 O máa kú sórí òkè tí o fẹ́ gùn yìí, a ó sì kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ,* bí Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe kú sórí Òkè Hóórì+ gẹ́lẹ́, tí wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀, Jóṣúà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
50 O máa kú sórí òkè tí o fẹ́ gùn yìí, a ó sì kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ,* bí Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe kú sórí Òkè Hóórì+ gẹ́lẹ́, tí wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,
2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+