Diutarónómì 26:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Níkẹyìn, Jèhófà fi ọwọ́ agbára mú wa kúrò ní Íjíbítì, pẹ̀lú apá tó nà jáde,+ àwọn nǹkan tó ń bani lẹ́rù, àwọn àmì àtàwọn iṣẹ́ ìyanu.+ Lúùkù 24:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó bi wọ́n pé: “Àwọn nǹkan wo?” Wọ́n sọ fún un pé: “Àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ sí Jésù ará Násárẹ́tì,+ ẹni tó fi hàn pé wòlíì tó lágbára ni òun nínú ọ̀rọ̀ àti ìṣe níwájú Ọlọ́run àti gbogbo èèyàn;+
8 Níkẹyìn, Jèhófà fi ọwọ́ agbára mú wa kúrò ní Íjíbítì, pẹ̀lú apá tó nà jáde,+ àwọn nǹkan tó ń bani lẹ́rù, àwọn àmì àtàwọn iṣẹ́ ìyanu.+
19 Ó bi wọ́n pé: “Àwọn nǹkan wo?” Wọ́n sọ fún un pé: “Àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ sí Jésù ará Násárẹ́tì,+ ẹni tó fi hàn pé wòlíì tó lágbára ni òun nínú ọ̀rọ̀ àti ìṣe níwájú Ọlọ́run àti gbogbo èèyàn;+