-
Sáàmù 119:98Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
98 Àṣẹ rẹ mú kí n gbọ́n ju àwọn ọ̀tá mi lọ,+
Nítorí pé ó wà pẹ̀lú mi títí láé.
-
-
Sáàmù 119:100Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
100 Mò ń fi òye hùwà ju àwọn àgbààgbà lọ,
Nítorí pé mò ń pa àwọn àṣẹ rẹ mọ́.
-