Ẹ́kísódù 20:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí ṣe ni Ọlọ́run tòótọ́ wá dán yín wò,+ kí ẹ lè máa bẹ̀rù rẹ̀ kí ẹ má bàa ṣẹ̀.”+ Diutarónómì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ì bá mà dáa o, tí wọ́n bá mú kí ọkàn wọn máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo,+ tí wọ́n ń pa gbogbo àṣẹ mi mọ́,+ nǹkan á máa lọ dáadáa fún àwọn àti àwọn ọmọ wọn títí láé!+
20 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí ṣe ni Ọlọ́run tòótọ́ wá dán yín wò,+ kí ẹ lè máa bẹ̀rù rẹ̀ kí ẹ má bàa ṣẹ̀.”+
29 Ì bá mà dáa o, tí wọ́n bá mú kí ọkàn wọn máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo,+ tí wọ́n ń pa gbogbo àṣẹ mi mọ́,+ nǹkan á máa lọ dáadáa fún àwọn àti àwọn ọmọ wọn títí láé!+