Àìsáyà 40:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ni ẹ lè fi Ọlọ́run wé?+ Kí lẹ lè fi sẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ tó máa jọ ọ́?+ Jòhánù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kò sí èèyàn tó rí Ọlọ́run rí;+ ọlọ́run bíbí kan ṣoṣo+ tó wà ní ẹ̀gbẹ́ Baba*+ ni ẹni tó ṣàlàyé Rẹ̀.+ Jòhánù 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run jẹ́ Ẹ̀mí,+ àwọn tó ń jọ́sìn rẹ̀ sì gbọ́dọ̀ máa jọ́sìn ní ẹ̀mí àti òtítọ́.”+
18 Kò sí èèyàn tó rí Ọlọ́run rí;+ ọlọ́run bíbí kan ṣoṣo+ tó wà ní ẹ̀gbẹ́ Baba*+ ni ẹni tó ṣàlàyé Rẹ̀.+