Ẹ́kísódù 20:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ohun tí ìwọ yóò sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí, ‘Ẹ̀yin fúnra yín rí i pé láti ọ̀run ni mo ti bá yín sọ̀rọ̀.+
22 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ohun tí ìwọ yóò sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí, ‘Ẹ̀yin fúnra yín rí i pé láti ọ̀run ni mo ti bá yín sọ̀rọ̀.+