Diutarónómì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ+ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀. Róòmù 1:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bí wọ́n tiẹ̀ ń sọ pé àwọn jẹ́ ọlọ́gbọ́n, wọ́n ya òmùgọ̀, 23 wọ́n sì yí ògo Ọlọ́run tí kò lè díbàjẹ́ pa dà sí ohun tó dà bí àwòrán èèyàn tó lè díbàjẹ́ àti àwọn ẹyẹ àti àwọn ẹ̀dá ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin pẹ̀lú àwọn ẹran tó ń fàyà fà.*+
8 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ+ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.
22 Bí wọ́n tiẹ̀ ń sọ pé àwọn jẹ́ ọlọ́gbọ́n, wọ́n ya òmùgọ̀, 23 wọ́n sì yí ògo Ọlọ́run tí kò lè díbàjẹ́ pa dà sí ohun tó dà bí àwòrán èèyàn tó lè díbàjẹ́ àti àwọn ẹyẹ àti àwọn ẹ̀dá ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin pẹ̀lú àwọn ẹran tó ń fàyà fà.*+