- 
	                        
            
            Léfítíkù 18:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        24 “‘Ẹ má fi èyíkéyìí nínú àwọn nǹkan yìí sọ ara yín di aláìmọ́, torí gbogbo àwọn nǹkan yìí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí mo fẹ́ lé kúrò níwájú yín fi sọ ara wọn di aláìmọ́.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Léfítíkù 18:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        28 Kí ilẹ̀ náà má bàa pọ̀ yín jáde torí pé ẹ sọ ọ́ di ẹlẹ́gbin, bó ṣe máa pọ àwọn orílẹ̀-èdè tó wà ṣáájú yín jáde. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Léfítíkù 26:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 “‘Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, tí ẹ ò bá fetí sí mi, tí ẹ ṣì ń kẹ̀yìn sí mi, 
 
-